Take a fresh look at your lifestyle.

Àkókó Guardiola Bí Olùkọ́ní Bayern Ló Ṣé Àkóbá Fún Bọ̀ọ́lù Germany Lágbayé – Schweinsteiger

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 405

Bastian Schweinsteiger tí sọ pé àkókò Pep Guardiola gẹ́gẹ́ bí olùkọ́ní Bayern Munich ṣé àkóbá sí àdínkù bọ̀ọ́lù Germany.

Guardiola jẹ́ olùkọ́ní Bayern ní ọdún 2013 tí Schweinsteiger gbábọ̀ọ́lù lábẹ́ rẹ̀ fún ọdún méjì ṣáájú kó tó lọ sínú ìkọ Manchester United ní ọdún 2015.

Lẹyìn tó gbà ìfé Àgbáyé 2014 FIFA World Cup ní Brazil, Germany tí kùnà láti ní ipá tó ni láárí kàn nínú àwọn eré-ìdárayá tó tẹle.

Wọ́n ní ìjákùlẹ̀ nínú ìpele àkọ́kọ́ níbí ìdíje àwọn ìfé Àgbáyé méjì tí wọ́n ti kópa ní ọdún 2018 àtí 2022.

Ní ọdún 2020 wọ́n kò lé kọjá ipele ẹ̀lẹ̀ní mẹrindilogun nínú ìfẹ yúrópù (European Championship).

Nígbàtí Ó nsọ̀rọ lórí talkSPORT, Schweinsteiger sọ pé ìpinnu ẹgbẹ́ àgbábọ́ọ̀lù Germany látí ti ìmòye bọ́ọ̀lù wọ́n pàdà ló dá wàhálà náà sílẹ̀.

“Atí wa gbàgbé àgbàrá wà àtí ọgbọ̀n wà kàà tó dojukọ gbá sí mí kín gbá sí ẹ lórí pápá.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button