Àjọ Àgbáyé (UN) Ń Béèrè Fún Bílíọ̀nù Mẹ́ta-Dín-Díẹ Dọla ($2.6B) Fún Iṣẹ́ Ọmọnìyàn Ni Sudan
Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà
Ìgbìmọ̀ élétó Ọmọnìyàn ti Àjọ Àgbáyé (UN) tí ń bẹ̀bẹ̀ fún Bílíọ̀nù Mẹ́ta-Dín-Díẹ Dọla ($2.56B) látí ṣé ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn tí àáwọ̀ tó ṣẹ̀lẹ̀ láàrín àwọn ọmọ Ogún Sudan àtí àwọn ẹgbẹ́ àlátákò ní Orílẹ̀-èdè Sudan ṣé àkóbá fún. Òṣìṣẹ́ àgbà Àjọ Àgbáyé (UN) kàn sọ èyí dì mímọ ní ni Ọjọ́rú, làkókò tí Ìgbìmọ̀ alasala àjọ náà tún n wà òwò díẹ̀ síi láti ṣé ìrànlọ́wọ́ fún àwọn tí wọ́n ṣá àsálà fún èmí wọ́n.
“Loni, àwọn ènìyàn mẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n mílíọ̀nù (25m), èyí tó jù ìdajì olùgbé orílẹ̀-èdè Sudan ló nílò ètò ìrànlọ́wọ́ Ọmọnìyàn àtí ìdáàbòbò, èyí tí kó wáyé ríi ní Orílẹ̀-èdè náà,” Ramesh Rajasingham.
Kọmisọna gíga tí Àjọ Àgbáyé fún àwọn Asasala (UNHCR), tí n ṣé afilọ àpapọ̀ pẹ̀lú ìgbìmọ̀ ìrànlọ́wọ́ ní Ọjọ́rú, sọ pé òún nílò ọ̀ọ́dẹ́gbẹ̀ta mílíọ̀nù dọla ($472m) látí ṣé ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn tó jù mílíọ̀nù (1milion Peoples) kàn lọ́ láàrín oṣù mẹfa tó mbọ̀.
Leave a Reply