Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu Rọ́ Àwọn Òṣìṣẹ́ Ológun Látí Dáàbòbo Ààlà Orílẹ̀-èdè

246

Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu ti rọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ògùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti máa Dáàbòbo àwọn ààlà Nàìjíríà lọ́wọ́ gbogbo ewú.

Ààrẹ náà tún sọ pé, pẹ̀lú ìkẹ́kọ́ tó dára ní ilè-ìwé gíga tí àwọn ológun (Nigeria Defence Academy NDA) Kaduna, àwọn Ọmọ-ogún Nàìjíríà lágbára látí mú òpin sí gbogbo àwọn ìwa-ìka, ìṣọtẹ̀ àtí ìwà-ipá tó ń ṣẹ́lẹ́ ní orílẹ̀-èdè náà.

Nígbàtí o nsọ̀rọ níbí isamisi ọgọ́ta ọdún tí Ilé-ìwé náà tí bẹ̀rẹ̀ ní Kaduna. Ààrẹ náà ṣé ìdánilójú ìrànlọ́wọ́ àtí àtìlẹ́yìn tí ìṣàkóso ìjọba rẹ̀ fún àwọn ológun Orílẹ̀-èdè náà.

Ààrẹ tí pàdà sí Abuja lẹyìn tó kópa níbí isamisi ọgọ́ta ọdún tí ìdásílẹ̀ Ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí Ààbò ‘Nigerian Defence Academy (NDA)’ ní Ìpínlẹ̀ Kaduna ní ọjọ́ Àbámẹ́ta.

Comments are closed.

button