Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Àwọn Aṣáájú Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àpapọ̀ Orílẹ̀-èdè
Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà
Ààrẹ Bola Tinubu tí ń ṣé ìpàdé pẹ̀lú àwọn olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àpapọ̀ ní Abuja.
Àwọn tó wà níbí ìpàdé náà ní Ààrẹ Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà, Ahmed Lawan, agbẹnusọ ilé ìgbìmọ̀ asojú-ṣófin, Femi Gbajabiamila àtí àwọn olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin mìíràn.
Voice of Nigeria jábọ pé ìdí ìpàdé náà kó tíì yé ẹnikan ṣùgbọ́n ó ṣeéṣe; kó ní í ṣe pẹ̀lú ọ̀rọ̀ àwọn aṣáájú ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kẹwàá (10th Assembly), tí yóò wáyé láìpẹ́ nínú oṣù yìí.
Tún kà nípa:Ààrẹ Tinubu Ń Ṣé Ìpàdé Pẹ̀lú Àwon Olórí Ààbò
Ní wákàtí díẹ̀ sẹyìn ní Ààrẹ ṣépàdé pẹ̀lú àwọn Olùdarí ààbò, tí wọ́n sọ fún ùn nípa ipò ààbò Orílẹ̀-èdè náà.
Ẹkùn rẹ̀rẹ̀ ìròyìn náà ń bọ̀ láìpẹ́…! Ẹ kú ojú lọ́nà..!!
Leave a Reply