Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari Fi Àwọn Àbá-dòfin Mẹ́ta Kán Ránṣẹ Sí Ìlé Ìgbìmọ̀ Aṣojú-ṣòfin

0 388

Ààrẹ Muhammadu Buhari tí gbé àwọn àbá-òfin mẹ́ta lọ́ sí Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣojú-ṣòfin fún àyẹwò.

Èyí ló farahàn nínú lẹta kàn tó kọ sí Agbẹnusọ Hon. Femi Gbajabiamila, èyítí o ká ní àpéjọ wọ́n ní ọjọ́ Ajé.

Àwọn àbá-dòfin náà ní: igbero ètò ìṣúná 2023 tí Olú-ìlú orílẹ-èdè yìí FCT, igbero ètò ìṣúná 2023 tí ìdàgbàsókè Niger/Delta (NDDC), Code of Conduct Bureau (CCB), ìwé òfin Tribunal 2022 àtí àtúnṣe ìwé òfin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà 2022.

Agbẹnusọ ọ̀ún ká lẹta náà sí etí àwọn akẹgbẹ rẹ̀, o sí fí wọ́n lé àwọn élétó wọ́n gbogbo lọ́wọ́ fún àgbéyẹ̀wò.

Lekan Orenuga

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button