Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari Ṣe Ìpàdé Pẹ̀lú Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Poland.

0 243

Ààrẹ Muhammed Buhari ṣe ìpàdé ààrẹ orílẹ̀-èdè Poland, Ààrẹ Andrzej Duda níbi tí wọ́n tí sọrọ to kàn orilẹ èdè méjèjì, ìpàdé èyí tí yóò mú àwọn ààrẹ méjèjì tọ wọ́ bò we fún ìrẹ́pọ̀ tó dán mọ́rán làrin ìlú méjèèjì.

Èyí wáyé nígbà tí ààrẹ Muhammed Buhari gbà ààrẹ naa ni àlejò ní ilé ìjọba ti Abuja

 

Oyébísí Adégbíté

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button