Take a fresh look at your lifestyle.

Kò Sí Ìgbàláàyè Fún Ìpínlẹ̀ Láti Ra Nǹkan Ogun

0 285

Ìjọba àpapọ̀ ti fi léde pé, òhun kò ì tíi ̀fi ọwọ́ si fún ìpínlẹ̀ kankan láti ra nnkan ogun ìgbàlódé fún àwọn ọmọ ogun abẹ́lé rẹ̀.

 

Agbenusọ ìjọba àpapọ̀, Garba Shehu sọ pé kò sí ìgbàláàyè fún ẹnikẹ́ni tàbí ìjọba ìpínlẹ̀ láti ra nǹkan ogun lọ́nà àìtọ́. Àti pé ìjìyà tí ó tóbi wà fún ẹnikẹ́ni tí ó bá se bẹ́ẹ̀ léyìi ́tí àwọn agbófinró sì ti wà ní ojú ni alákàn fi ń sọ́ri.́

 

Ìjọba àpapọ̀ gbé oríyìn fún ìjọba ìpínlẹ̀ fún ipa ribiribi tí wọ́n ń kó nínú ètò ààbò. Ní pàápàá, Ààrẹ fi ìdùnnú rẹ̀ hàn fún ipa mánigbàgbé tí ìpínlẹ̀ ń kó nínú ètò ààbò, ó sì se ìkìlọ̀ láti má se sọ àkóso ètò ààbò di ọ̀rọ̀ òsèlú.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button