Take a fresh look at your lifestyle.

Tobi amusan tún ti fakọyọ nínú ìdíje eré sísá àjọ commonwealth

0 464

Tobiloba Ayomide Amusan tún ti kọ ìtàn ti kò lè parẹ́ gẹ́gẹ́ bí eléré ìdárayá àkọ́kọ́ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ẹlẹ́ẹ̀kejì nínú ìtàn láti bá orílẹ-èdè Nàìjíríà gba ipò kíní nínú ìdíje eré 100m àjọ Commonwealth.

Ọmọ ọdún, márùnlélógún náà tún ti ni 12.30 aaya ninu ìgbìyànjú rẹ láti gba àmì-ẹyẹ góòlù.

Amusan, eléré ìdárayá àgbáyé, ti di akoni rekoodu lagbaye nínú ìdíje naa, ó tún di eléré ìdárayá eré àti pápá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà akọkọ ti o gba góòlù ni lemeji ninu Idije naa, àti ẹni tó gba ipò kíní lẹmẹta léra léra.

 

Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button