Àwọn Mínísítà fọwọ́sí ètò Àbojútó Àti àgbéyẹ̀wò ní orílẹ̀-èdè
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Ìgbìmọ̀ Aláse àpapọ̀ ti fọwọ́sí ètò ìmúlò tuntun fún ìgbékalẹ̀ iṣé àbojútó àti àgbéyẹ̀wò ní Nìàjíríà.
Eto naa ni amọ si Eto Abojuto ati agbeyẹwo Orilẹ-ede.
Minisita fun eto iṣuna, inawo ati eto orilẹ-ede, Zainab Ahmed fi eyi han lasiko ti o n ṣe alaye fun awọn oniroyin Ile-iṣẹ aarẹ ni ipari ipade minisita ti ọsẹ yii, ti aarẹ Muhammadu Buhari dari.
![]()
Ahmed sọ pe, eto imulo naa yoo ṣe iranlọwọ lati mu ilọsiwaju to dara ba igbe aye awọn ara ilu ati idagbasoke-ọrọ-aje orilẹ-ede.
Leave a Reply