Take a fresh look at your lifestyle.

A yóò ṣa gbogbo ipá wa láti ran Sẹ́nétọ̀ tó wà nínú làásìgbò lọ́wọ́

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 270

Olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣojú-ṣòfin Nàìjíríà, Aṣojú Fẹ́mi Gbàjàbíàmílà sọ pé òun ti pá láṣẹ fún Ìgbìmọ̀ aṣojú Nàìjíríà ní UK, láti fún Sẹ́nétọ̀ Ike Ekweremadu, ní gbogbo ìrànlọ́wọ́ tí ó nílò lórí mímú tí wọ́n mu sílẹ̀ ní United Kingdom.

O sọ pe, o tun ti paṣẹ pe ki wọn yan agbẹjọro ilu-ọba  fun.

Adari ile naa tun sọ pe, pẹlu ipọnju Ekweremadu, o  ṣi jẹ ọmọ ilu Naijiria ti o ni ọwọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button