Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ CAF kí Ààrẹ FIFA Infantino kú Oríire Fún Ayẹyẹ Ọdún Mẹ́wàá Rẹ̀ Bí Ààrẹ FIFA

103

 

Ààrẹ àjọ Confédération Africaine de Football (CAF), Dókítà Patrice Motsepe, kí Gianni Infantino kú oríire fún ìdarí ọdún mẹ́wàá rẹ tó tayọ̀ gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ FIFA.

Nínú gbólóhùn kan, àjọ ìṣàkóso ilẹ̀ Afrika yìn Infantino fún “ìdarí tó tayọ̀” àti ìfaradà rẹ̀ sí ìdàgbàsókè bọ́ọ̀lùni ilẹ̀ Adúláwọ̀.

Láti ìgbà tí wọ́n ti yàn án ní oṣù Kejì ọdún 2016, ọ̀gbeni nfantino ti ṣe àkóso àkókò ìdàgbàsókè ètò àti ìṣúná owó tó ṣe pàtàkì nínú eré idaraya àgbáyé.

Àjọ CAF jiyan pe awọn atunṣe wọnyi ti ṣe anfani pataki fun awọn ẹgbẹ mẹ́rìnléláàdọta ti ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ rẹ̀.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button