Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà–Türkiye tẹ̀síwájú lórí igbiyanju fún ọ̀rọ̀ ìtọ́jú pẹ̀lú iwe àdéhùn

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

58

Naijiria ti buwọ́lu ìwé àdéhùn (MoU), lórí ìṣọ̀kan àti ìwà lálàáfíà àwùjọ,  tí èyí sì jẹ́ ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ pàtàkì ní ṣíṣe ìfilọ́lẹ̀ àti ìgbòòrò ẹ̀ka ìtọ́jú orílẹ̀-èdè.

MoU naa, iwe adehun ẹlẹẹkẹsan ti awọn mejeeji buwọlu ni Ankara, Türkiye, lasiko abẹwo orilẹ-ede naa si Aarẹ Bola Ahmed Tinubu gbe ọrọ itọju ni ọkan gbogi ifẹsẹmulẹ  ẹya idile bii idagbasoke orilẹ-ede labẹ Agbekalẹ Atunṣe Ireti.

Minisita fun ọrọ awọn Obirin ati Idagbasoke Awujọ ti Naijiria, Hajiya Iman Suleiman-Ibrahim, buwọ lu fun Naijiria, nigba ti Minisita fun Ẹbi ati Iṣẹ Awujọ, Mahinur Özdemir Göktaş to ṣoju Türkiye buwọluu.

Adehun yii yoo wa fun ọdun kan laarin orilẹ-ede mejeeji ti o si wa fun lati ṣatunṣe idagbasoke awujọ nipasẹ ajọṣepọ to fẹsẹmulẹ.

Iwe adehun yii yoo kọkọ ṣiṣe lori ilana iṣẹ orilẹ-ede lori Ẹbi ni ipari ọdun 2026, pẹlu Ipataki Itọju bii opo to ṣe pataki.

Ilana ko gbogbo Ipataki Itọju lapapọ lati pese iranlọwọ to dangajia fun awọn ipo itọju ti ko lowo lori ti awọn obinrin ati ẹbi n gbe.

Comments are closed.

button