Ìyàwó Ààrẹ Orílẹ-èdè yìí ti rọ àwọn ọmọ orílẹ-èdè yìí látì tẹwọ gba ohun alumọni agbara fún àyíká tó mọ́ tótó.
Ó sọ èyí nibi ọrọ rẹ láti sami sì ayeye ọjọ ayika to mọ́ toto agbaye ọdún 2026.
Arabinrin akọkọ rọ gbogbo ọmọ Naijiria láti sa ipa tiwọn nipa jíjẹ kí àyíká wà daradara kí o sì máa tẹ siwaju bẹẹ.
Ayẹyẹ ọjọ ayika to mọ́ toto agbaye ní wọn a máa ṣe ní ọjoojọ́ kerindinlogbon, oṣù kínní ọdọọdún fún itaniji ayika to rẹwa to mo toto láti dènà ewu inu afẹfẹ.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san