Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè Egypt Ti Fi Ẹsẹ̀ Ìbáṣepọ̀ Àwọn Ati Orílè-èdè US Músẹ̀ Ṣinṣin.

188

Mínísítà òkè òkun fún Orílè-èdè Egypt, Badr Abdel-Aty kí igbákejì Akọ̀wé Orílè-èdè US Christopher Landau káàbò sí Cairo fún ìtèsíwájú ìbásepọ̀ to san mórán láàrin Orílè-èdè méjèjì.

Àwọn méjèèjì sọ̀rọ̀ nípa àtúnṣe sí àwọn Orílẹ̀-èdè míràn bi Gaza, Sudan ati Áfíríkà.

Orílẹ-èdè Egypt ni nípa Orílè-èdè Gaza àwọn yóò tubo ṣe atilẹyin fún wọn.

Wọn ni àwọn yóò mú ìdàgbàsókè bá arin ìlú ati agbègbè,sí sì àwọn òpópó-ònà láàrin àwọn ìlú gbogbo. Fún ìbáṣepọ̀ to dan móra ati ìdàgbàsókè

Wọn ni àwọn yóò pé fún àlàáfíà fún Orílè-èdè Sudan àti isẹ ìjoba òṣèlú ti yóò mú àwọn ènìyàn wa ni iṣọkan ati àlàáfíà.

Comments are closed.

button