Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Rivers Tún Jẹrìí Sí Ìtẹ̀síwájú Àwọn Òṣìṣẹ́

Lekan Orenuga

120

Ìjọba ìpínlẹ̀ Rivers ní Gúúsù-gúúsù Nàìjíríà tí ṣé àtúnṣe fún ìtẹ̀síwájú àwọn òṣìṣẹ́ ní ìpínlẹ̀ náà nígbà tí wọ́n ṣe àgbékalẹ̀ ètò àtúnṣe ilé-iṣẹ́ ìpínlẹ̀ Rivers.

‎ Olùdarí Ìpínlẹ̀ Rivers, ‘Vice Admiral’ Ibok-Ete Ibas, ṣé ìpinnu ní ìparí tí ìdánilékọ̀ọ́ ọlọ́jọ́ mẹ́rin tó ṣètò nípasẹ̀ Ìjọba Ìpínlẹ̀ Rivers ní ìfọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ‘National Institute for Policy and Strategic Studies (NIPSS).’

‎ Ìdánilékọ̀ọ́ náà, tó wáyé ní ‘Port Harcourt’, ní á pèsè fún àwọn Akọ̀wé àgbà, Àwọn alabojuto Ìjọba ìbílẹ̀, Àwọn Olùdarí, àti àwọn òṣìṣẹ́ àgbà pẹ̀lú ẹ̀kọ́ ọgbọ̀n látí wá kọ àwọn àtúnṣe ìjọba.

Comments are closed.

button