Igbákejì ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ọ̀jọ̀gbón Yẹmí Osinbajo ti ṣàbẹ̀wò sí ìdílé Dangote àti Dantata ní Kano láti bá wọn kẹ́dùn lórí ikú ọmọ wọn, arákùnrin àti bàbá wọn, Alh. Sani Dangote.
Oloogbe Sani Dangote, ti o jẹ aburo si ọlọrọ julọ ni Afirika, Aliko Dangote, ku ni ọjọ Aiku.
Ọ̀jọ̀gbón Osinbajo ba awọn ebi Dangote ati Dantata, ati awọn eniyan ipinlẹ Kano lapapo kẹdun. O ni ki i ṣe adanu fun idile oloogbe ati ipinlẹ Kano nikan ni iku naa jẹ, ṣugbọn ti orilẹ-ede lapapọ.
Tolulọpẹ Akinṣẹyẹ
Leave a Reply