Take a fresh look at your lifestyle.

Ọmọ Ogun Afipagbajọba Kéde Ijọba Ọdún Márùn-ún Ìṣèjọba Alágbádá

241

 

Ìjọba Ologun Ile Niger ti kéde ọdún márún idajọba padà sọ́wọ́ ijọba alagbada ti òfin la kalẹ láti ọjọ́ Ọjọ́rú gẹgẹ bí òfin iyipada tuntun ti wọ́n sẹ̀sẹ̀ buwọ́lù.

 

Ikede yìí tẹ̀lé ètò ìdìtẹ̀gbàjọba ọdún 2023 tó sì ààrẹ Mohamed Bazoum nípò. Bí ti ijọba ologun ní orílẹ̀-èdè Málì àti Burkina Faso, Ijọba ologun lé àwọn ológun ilẹ̀ Faransé àti ti gẹẹsi tèfètèfè ṣùgbọ́n wọn ń wá atilẹyin ilẹ̀ Russia ni ọnà láti dojú ìjà kọ àwọn ologun míràn tó leè dojuko wọn.

 

Ètò ọlọdún marun náà wà ní ìbámu ti wọn ṣètò rẹ ni osù Kejì ọdún lẹ́yìn ètò iforowerọ̀ àjọ apapọ orílè-èdè naa.

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button