Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Aṣòfin Nàìjíríà Yóò Tẹ̀síwájú Nínú Àjọṣepọ̀ Ìdàgbàsókè Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Kenya

Lekan Orenuga

165

Ilè Ìgbìmọ̀ Aṣojú ṣofin yóò tẹ̀síwájú nínú àjọṣepọ̀ wọ́n pẹ̀lú Kenya lórí ìdàgbàsókè àwọn apá pàtàkì tí ètò-ọrọ àjé.

‎ Alága, Ẹgbẹ́ Ilé aṣòfin Orílẹ̀-èdè méjèèjì, Ọ̀gbẹ́ni Abdullahi El-rasheed, fúnni ní ìtọ́kasí ní ìpàdé kán pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tí Ìgbìmọ̀ gíga Kenya sí Nàìjíríà, ní Abuja.


‎ O sọ pé ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Nàìjíríà àti Kenya tí tẹ̀síwájú láti dàgbà ní àwọn agbègbè oríṣiríṣi, ní pàtàkì ìṣòwò, ìdókòwò, àti àtìlẹ́yìn ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí ìpele àgbáyé.

Comments are closed.

button