Ìkọ Liverpool tí wá nípò láti kópa nínú ìkọ ẹlẹni mẹ́rìndínlógún 16 nínú ìdíje ‘Europa League’ bó ṣé bóri ìkọ LASK tí ‘Australia’ pẹ̀lú ayò 4-0 ní ‘Anfield,’ bí àkọ́ni-mọ́ọ̀gbá Jürgen Klopp ṣé sọ́ pé ó ṣé pàtàkì látí gbégbá orí òkè nínú lórí tábìlì.

Jürgen Klopp sọ pé o jẹ́ àbájáde tó dára, bí wọ́n ṣé ń múra sílẹ fún àwọn òní rúùrù Ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́. Liverpool yóò ní ànfààní látí kópa tẹ̀síwájú nínú ìparí ìdíje náà láti dé òpin ẹlẹni mẹ́rìndínlógún 16 tó kẹyìn.
Àwọn àbájáde èsì ìfẹsẹ́wọ́nsẹ́ tí Ọjọ́bọ̀
TSC Backa Topola 0-1 West Ham
Freiburg 5-0 Olympiacos
AEK Athens 0-1 Brighton & Hove Albion
Marseille 4-3 Ajax
Sparta Prague 1-0 Real Betis
Rangers 1-1 Aris Limassol
Atalanta 1-1 Sporting CP
Sturm Graz 0-1 Rakow Czestochowa
Liverpool 4-0 LASK
Toulouse 0-0 Union St.Gilloise
Maccabi Haifa 0-3 Rennes
Villarreal 3-2 Panathinaikos
Servette 1-1 Roma
FC Sheriff 2-3 Slavia Prague
BK Hacken 0-2 Leverkusen
Molde 2-2 Qarabag FK.
Leave a Reply