Àkọ́ni-mọ́ọ̀gbá Liverpool Sọ́ Pé Ó Ṣé Pàtàkì Látí Wà Lókè Tábìlì ‘Europa League’
Ìkọ Liverpool tí wá nípò láti kópa nínú ìkọ ẹlẹni mẹ́rìndínlógún 16 nínú ìdíje 'Europa League' bó ṣé bóri ìkọ LASK tí 'Australia' pẹ̀lú ayò 4-0 ní 'Anfield,' bí àkọ́ni-mọ́ọ̀gbá Jürgen Klopp ṣé sọ́ pé ó ṣé pàtàkì látí gbégbá orí òkè nínú…