Mínísítà fún ètò ọ̀gbìn àti ààbò fún oúnjẹ (FMAFS) Ṣẹ́nitọ̀ Abubakar Iyari àti Mínísítà fún ìpínlẹ̀, Ṣẹ́nitọ̀ Aliyu Sani Abdullahi ṣe ìbẹ̀wò sí ọ̀gbìn oúnjẹ whaet ni ọjọ́ keje oṣù kọkànláọjọ́ fun ètò ọ̀gbìn ti ijoba àpapọ gbé kalẹ.
Ètò yìí wa ni abẹ́ àkọsọ Agro-Pocket.
Bi a ba gbagbé àjọ AgroNigeria ni ki ìjọba àpapọ̀ ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn àgbẹ̀ tó lè ní egberun méjì fún ìdàgbàsókè ohun ọ̀gbìn wheat
Leave a Reply