Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra pè fún ìṣọ̀kan láàrin ìjọ kìrísítíẹ́nì

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 240

Gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Ọ̀jọ̀gbọ́n Chukwuma Soludo ti pè fún ìṣọ̀kan àti àgbọ́yé láàrin ìjọ oríṣiríṣi kìrísítíẹ́nì, fún iṣẹ́ pàtàkì àti èròńgbà kannáàn.

Gomina Soludo pe ipe yii nigba ti o n gbalejo Alufa Nuncio ti orile-ede  Czech, Ẹni ọwọ Alufa Jude Thaddeus Okolo, laarin awọn ero, ni ile igbafẹ gomina, ni Amawbia, ní Awka, olu ipinlẹ naa.

Eleyi  di mimọ nipasẹ alaye kan ti Akọwe oniroyin fun gomina, Christian Aburime fi sita.

O wa sọ ojuṣe awọn kìrísítíẹ́nì lati ṣagbelarugẹ alaafia ati idajọ ododo lagbaaye, paapaa julọ laarin igbooro hila hilo oloṣelu ati ibaraẹniṣepọ.

Gomin tun wa tẹnumọ pataki lati fọwọwẹwọ ninu iṣọkan, ifẹ, ati ibọwọ, lati ṣe igbelarugẹ iyanju ija ati  iwosan ni agbegbe ati lagbaaye.

O wa pe akiyesi wọn si pe  ijọ kọọkan lo ni pataki itan rẹ, iṣe, ati isin ti o le fun ni lagbara ati mu igboye igbagbọ kirisitiẹni gbooro si, a tunbọ le fidi agbọye eleyii nipasẹ  ṣiṣajọyọ iyatọ, iṣọkan ati atilẹyin mulẹ.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button