Take a fresh look at your lifestyle.

Ológun yóò ṣèwáádí ẹ̀sùn àìróúnjẹ jẹ àwọn ọmọ ogun tó wà lójú ogun

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 195

Ọ̀gá àgbà fún àwọn òṣìṣẹ́ ológun, COAS, AjagunTaoreed Lagbaja ti pè fún ìṣèwáádí ẹ̀sùn àìróúnjẹ jẹ àwọn ọmọ ogun tó wà lójú ogun ní Gúsù ilà oòrùn.

Ninu ọrọ kan ti adari eto ibaraẹniṣepọ fun awọn ọmọ ogun, Ajagun Onyema Nwachukwu, ti ologun Naijiria (NA) buwọlu, o sọ pe wọn pe akiyesi oun si ẹsun yii ati pe o ṣe pataki lati yanana rẹ pe iwa daradara awọn ọmọ ogun to wa labẹ iṣejọba ologun to wa lori oye yii ṣe pataki si wọn ninu awọn eto miiran tabi nnkan ṣise.

Igbe aye rere awọn ọmọ ogun jẹ ọkan pataki ninu opo mulero aṣẹ COAS leyii to jẹpe àti pese “iṣakoso to muna doko,” lati ṣe iwuri fun awọn ọmọ ogun.

Ologun Naijiria wa sọ pe “oun ko fọwọ yepẹrẹ mu ẹsun naa ati pe ọga agba fun awọn oṣiṣẹ ologun (COAS) AjagunTaoreed Lagbaja ti paṣẹ iṣewaadi lori ẹsun naa lati mọ idi abajọ.”

O wa n fi da gbogbo ara ilu ati ọmọ ogun Naijiria loju pe iṣewaadi to tọ yoo waye lati ri idi ọrọ naa

O tun sọ siwaju ninu ọrọ naa peThe statement further said; “tigbe aye rere awọn ọmọ ogun wa lookan aya oun, pẹlu ounjẹ jijẹ wọn.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button