Àjọ kan tí kìí se ti ijoba, Defenders of Constitutional Democracy (DCD) ti gba ààrẹ Tinubu ni ìmọ̀ràn láti yan Olùyẹ̀wé Owó-wò àgbà ijoba àpapọ̀. .
Alága ẹgbẹ́ náà, Alhaji Abdullahi Aliyu, lo sọ èyí ní Abuja.
Ó kẹ́dùn pé àyè àìsí Olùyẹ̀wé Owó-wò àgbà tó yanrantí ti fi ààyè sílẹ láti jẹ kí ìwà jẹgúdú-jẹrá kó gbilẹ̀ ní ẹ̀ka ti Ministries, Departments and Agencies (MDAs) ti orílẹ̀-èdè yìí.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply