Ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣétan láti ṣé ètò ààbò fún ipé àti Intánẹ̀ẹ́tì nílẹ̀ Àfírìkà, èyí tó lágbárá láti mú òún ọtún bá ẹ̀ká nàá nílẹ̀ Àfírìkà.

Minisita fun Ibaraẹnisọrọ, òún ọtún ati idagbasoke eto ọrọ aje, Dokita Bosun Tijani sọ eyi nibi apejọ iṣakoso Intanẹẹti Afirika to ṣẹṣẹ pari ni Abuja.
Tijani sọ pe iṣakoso ti Aare Bola Ahmed Tinubu ti pinnu lati ṣe agbekalẹ awọn ifowosowopo pataki ati awọn ijiroro agbaye lati ṣaṣeyọri awọn ibi-afẹde wọnyi.

Igbakeji Alase ti NCC, Ọjọgbọn Umar Danbatta, nibi ibẹrẹ ati ipari ti ipade ati ijiroro igbimọ naa, ṣe ilanilọyẹ ati imọran lori NCC lati pese aabo fun ipe ati ilana ayelujara ni ilẹ Afirika.
Leave a Reply