Ẹgbẹ́ Òṣèlú People’s Democratic Party (PDP) nínú àtẹ̀jàde kan ti kọ èsì àbájàde Ìdájọ Ilé ẹjọ́ tó fi òùntẹ̀ lù ìjàwé olúborí ààrẹ Bola Ahmed Tinubu; àti igbákejì rẹ̀, Kashim Shettima, nínú ibò ààrẹ tí ó kọjá.
Nínú àtẹ̀jàde ti akọ̀wé ẹgbẹ́ PDP, Ọ́nárébù Debo Ologunagba buwọ́lù ní ọjọ́ Ọjọ́rú, Ó sọ pé ìdájọ náà takò ìdí àti òdodo tí wọ́n fi fi sí iwájú ilé ẹjọ́, àti pé ó tako òfin ìbò tó se gbógì, ó tun takò òfin àti ìlànà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply