Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́  Àwọn Olóògùn Òyìnbó Yan Adarí Tuntun.

0 181

Ẹgbẹ́ àwọn tó n tá ogun òyìnbó ni Orílẹ̀-èdè Niger (ACPN) ti pé fún àtúnse lori wí pé kò sí àwọn òṣìṣẹ́ tó pọ̀ ní àwọn ilé ìwòsan ìjọba.

Nínú atẹjade láti ọwọ́ alága ẹgbẹ́ náà Adewale Oladigbolu, ní ọ̀rọ̀ yii tí jáde lẹ́yìn ìpàdé pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tokun , ìpàdé tó dá lórí bi àwọn ile ìwòsan ìjọba yóò ṣe ní àwọn òṣìṣẹ́  ni àní tó.

Níbi ìpàdé yìí ní yíyan àwọn adarí tuntun Míràn

Oladigbolu ni wọn Yan gẹ́gẹ́ bí alága fún ẹgbẹ́ náà, Ìyáàfin Bridget Aladi ni wọn Yan gẹ́gẹ́ bí igbákejì rẹ, nígbà tí wọn yan

Omokhafe Ashore jẹ́ akọ́wẹ́ ẹgbẹ́.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button