Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè India Fìtàn Balẹ̀, Ikọ̀ Oníwàdí Gúnlẹ̀ Sórí Òṣùpá

0 210

Orílẹ̀-èdè India ti di Orílẹ̀-èdè kẹrin tó máa gúnlè sori òṣùpá lẹyìn ti ikọ̀ Indian Space Research Organisation’s Chandrayaan-3 ri èyí se lórí ọ̀pá osupa gúsù.

“Àkókò yi jẹ́ àkókò tí a ko leè gbàgbé, o kàyéfì! Ó jẹ́ igbe àṣeyọrí fún ilẹ India tuntun,” Ààrẹ Narendra Modi sọ èyí bí ó se ń fi àsìá ilẹ̀ India bí ó se ń wòó wọ́n láti orílẹ̀-èdè South Africa níbi tí o ti lọ se ìpàdé.

Onímọ̀-ẹ̀rọ àti àwọn àgba òṣìṣẹ́ pateẹ́wọ́,  wọ́n pariwo, wọ́n dì mọ́ ara wọn bi àwọn tó lọ sí inú sánmọ náà se balẹ̀ gudẹ̀, àwọn ènìyàn ní ilẹ̀ India sí bẹ̀rẹ̀ àjoyọ̀ pẹ̀lú ijó ni gbogbo agbègbè.

Chandrayaan-3 ni India fi lọ́lẹ̀ pẹ̀lú oye owó tó lé diẹ̀ ni bílíọ̀nù mẹ́fà rupees ($74 million).

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button