Ààrẹ àná fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari, tí fi ayọ rẹ hàn lórí ayẹyẹ ọjọ́ ìbí Ọdún Méjìlélọ́gọ́rin tí Ààrẹ Ológun tẹ́lẹ̀ rí fún Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ọ̀gagun Babangida pé lórí ilẹ alààyè.
Nínú atẹjade kan láti ọwọ́ agbẹnusọ rẹ , Ààrẹ tẹ́lẹ̀ rí ṣe àpèjúwe Babangida gẹ́gẹ́ bí Akinkanju Okunrin ti Óruko rẹ ko le parẹ nínú ìwé àwọn akọni.
Ó ni nínú ìwé ìtàn Orílẹ̀-èdè pẹ̀lú, Oruko Babangida ko le parẹ láíláí.
Ó wa ki Babangida àti ádùrá wí pé Ọlọrun a túbọ̀ lọ́ra Èmi rẹ pẹ̀lú àlàáfíà tó pé yé.
Leave a Reply