Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-èdè China Àti India Se Ìlérí Láti Wà Ní Ìrẹ́pọ̀ Ní Ti Àlà Ilẹ̀

0 228

 

Orílẹ̀-èdè China àti India se ìleri láti wà ni àlàáfíà àti Irẹpọ ní ti àla ilẹ̀ wọn. Àjọ ẹ̀ka ti ètò ààbò orílẹ̀-èdè China sọ èyí.

Àwọn méjèjì jọ ní àpérò àti àjọsọ tó gúnmọ́ lórí LAC (line of actual control) àti àlà ilẹ̀. Mínísírì sọ èyí.

Wọ́n tún forí barí láti yanjú gbogbo ááwọ̀ kí ááwọ̀ tó leè wà láàrin àwọn méjèjì ní ìtùnbí ìtùnbí àti ní ti ipasẹ̀ ológun.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button