Ààrẹ Bọla Tinubu ti kéde pé ìjọba òun ti gbáradì láti mójútó ìpeniníjà tí kò jẹ́ kí ìpèsè iná ṣe déedé ní orílẹ̀ -èdè.
O ni ijọba oun yoo pese idahun si oriṣiriṣi ipeninija jakejado ikọ ina kaakiri, pẹlu itura si wahala to ti wa nilẹ tipẹ ati atunṣe pipese rẹ lọpọ fun awọn ọmọ Naijiria.

Aarẹ Tinubu pe ipe yii ni ọjọ Ẹti, ní Abuja, nibi ifilọlẹ 350MW tuntun ti Gwagwalada Independent Thermal Power Plant (Phase 1), nibi ti o ti rọ Ajọ NNPC ati awọn alajọṣepọ rẹ lati ṣe iṣe akanṣe to munadoko laarin ọdun mẹta ti o ṣeleri pe yoo pari, ti o si tẹnumọ pe, “ọdun mẹta gbọbọ jẹ ọdun mẹta ni.”

Leave a Reply