Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Tinubu ṣèdárò àwọn tó fara káàsá ìjàm̀bá ọkọ̀ ojú omi ní ìpínlẹ̀ Kwara

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 237

Ààrẹ Bla Tinubu banújẹ́ lórí ìjàm̀bá ọkọ̀ ojú omi tó ṣelẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Kwara, léyìí tó gba ẹ̀mí ọ̀pọ̀ ènìyàn.

Gẹ́gẹ́ bí a ṣe gbọ́, ìjàm̀bá náà gba ẹ̀mí ènìyàn to lé lọ́gọ́rùn ún tí ó jẹ́ àlejò níbi ìgbéyàwó kan, ní abúlé Egbu, ní ìjọba ìbílẹ̀ Patigi, ní ìpínlẹ̀ náà.

O wa n rọ ijọba ipinlẹ  Kwara àti awọn ile-iṣẹ ijọba apapọ ti iṣẹ wọn ba jọ mọ, lati ṣewadii nnkan to le ṣokunfa iru ijamba naa,aarẹ Tinubu wa pinnu pe ijọba oun yoo siṣẹ lori ipeninija ti o ń koju lilọ bibọ lori omi lorilẹ-ede lati pese aabo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button