Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn arìnrìnàjò lọsí ìlú mecca yóò san owó tótó mílíọ̀nù méjì àti àbọ̀ fún ìrìnàjò hajj odún 2023- Àwọn aláàkóso FCTA

0 231

 

Oludari àwọn alakoso, Malam Muhammad Nasiru Danmalam lo sọ ọrọ yii lasiko ti o fun awọn agba oṣiṣẹ ni àbọ̀ níbi ipade akọkọ Hajj lọ si Saudi Arabia lati se eto fun Hajj ọdun 2023

 

Malam Muhammad sọ wí pé aṣẹ yii pọn dandan lati rii daju wipe wọn se àkójo orúko àwọn ti yóò lọ si irinajo náà

 

Oludari náà tun ṣe afikun pe, awọn ti o san owo ti ko si ni anfani lati lọ fun ti ọdun to kọja latari idi kan tabi omiran, ki wọn wa ri àwọn alakoso pẹlu ẹri to daju wi pe wọn san owo lati le fi han wipe Hajj ti ọdun yii wu wọn lọ tabi ki wọn gba owo wọn pada.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button