Adarí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Femi Gbajabiamila ti pe àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti wá ní ìrẹ́pọ̀ àti ìsọ̀kan ṣáájú ìdìbò ọdún 2023.
Ó ṣe ìkíni káàbọ̀ sí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn pọ̀pọ̀ ṣinṣin ọdún, kèrésímesí àti ọdún tuntun
Adarí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin dupẹ gidigidi lọ́wọ́ àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba,ti wọn fí okun ati agbára ṣiṣe wọn fún àlàáfíà àti ìlọsíwájú orílẹ̀-èdè yìí.
Ó ní ohun fojú sónà fún ìbáṣepọ̀ tó dán móra nínú ọdún kí àṣeyọrí le tẹ̀lé gbogbo iṣẹ́ láwọn ba ṣe.
Leave a Reply