Ilé-iṣẹ́ Ìlera tí Ìpínlẹ̀ Anambra tí gbá áwọn ami-ẹyẹ mẹ́ta tí orílẹ̀-èdè lóri ikọ-ẹgbẹ látí ọdọ Ilé-iṣẹ́ Ìlera tí ìjọba, Ẹ̀tẹ̀, ikọ-ẹgbẹ àtí ẹ̀kà ètò Ọgbẹ́-inú ti gbogbo ọmọ Orílẹ̀-èdè yìí.
Kọmisana fún Ìlera Anambra, Dókítà Afam Obidike tún sọ́ bí Gómìnà Charles Soludo ṣé ń ṣé àtìlẹ́yìn ìlọsíwájú ẹ̀kà Ìlera tí ìpínlẹ̀ náà. Dókítà Obidike sọ pé àwọn ami-ẹyẹ tí ẹ̀kà ikọ-ẹgbẹ gbà ní abẹ́ Ilé-iṣẹ́ ìjọba rẹ̀ sí iṣẹ́ takuntakun tí Alàkóso ètò ikọ-ẹgbẹ.

“Ẹyẹ yìí yóò gbà gbogbo wà níyànjú láti tún sápá sí ní ọdún tó ń bọ̀ àtí pé Mò rọ́ gbogbo ènìyàn látí dúró ṣinṣin nìdí iṣẹ́ wọ́n.
“Gẹ́gẹ́ bíí olórí, ojúṣe ṣé rẹ̀ àti pé Mò gbọdọ gbóríyìn fún ẹ̀kà ikọ-ẹgbẹ tí wọ́n ṣé dáradára wọ́n sì lẹtọ ami-ẹri wọnyí láti ọwọ́ Orílẹ-èdè.”
“O ṣẹlẹ̀ pé ní ọdọọdún ní a má ń gbà àmì-ẹye tí tọdun yí tún jẹ́ mẹ́ta.
“Ni ìdí èyí, a ó sá gbogbo ipá wà látí ríi dájú pé a kò dúró níbí tí tọdun yìí dé.” Alàkóso ètò ikọ-ẹgbẹ, Dókítà Ugochukwu Chukwulobelu
Leave a Reply