Take a fresh look at your lifestyle.

Àjáabálẹ̀: Ààrẹ Tinubu Fọwọ́sí Òfin Ìlànà Ìdìbò 2026

118

Ààrẹ Bola Tinubu tí fọwọ́sí Àtúnṣe Òfin Ìlànà Ìdìbò 2026, ọjọ́ díẹ̀ lẹ́yìn tí Àjọ Olómìnira Elétò Ìdìbò tí Orílẹ̀-èdè (INEC) ṣàfihàn àkókò àti ìlànà ìdìbò gbogbogbòò fún ọdún 2027.

Ayẹyẹ ibuwọlu náà wáyé ní Ilé-iṣẹ́ Ààrẹ, Abuja, ní nkán bíi aago márùn ún (5:00 pm) irọlẹ ní Ọjọ́rú, pẹ̀lú àwọn olórí aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti Orílẹ̀-èdè yìí lẹyin ti àwọn aṣòfin náà tí buwọ́lù ìwé àṣẹ náà ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun.

‎ Àtúnṣe ránpẹ́ tó wáyé lẹ́yìn ariwo àwọn aráàlú lórí àtúnṣe sí ìlànà gbígbé èsì ìbò jáde lẹsẹkẹsẹ tí wọ́n bá tí dibo tán.

Comments are closed.

button