Take a fresh look at your lifestyle.

118

Ìjọba Nàìjíríà ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe àwọn òun pàtàkì nínú àdéhùn tí wọ́n tún ṣe pẹ̀lú Ẹgbẹ́ Àwọn Ọ̀gá Ilé-ẹ̀kọ́ gíga (ASUU).


‎ Mínísítà fún Ẹ̀kọ́, Dókítà Maruf Tunji Alausa, nínú ìkéde tí Olùdarí Ìròyìn, Boriowo Folashade, gbé jáde, sọ pé Ìjọba Àpapọ̀ ti ṣe ojúṣe rẹ̀ nípa bíbẹ̀rẹ̀ sí ní mú ìdàgbàsókè ìdá ọgọ́rùn (40%) nínú ọgọ́rùn-ún nínú Ìfúnni Àkọ́kọ́ (CAA) fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ASUU, bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kìíní oṣù kìíní ọdún 2026, ní ìbámu pẹ̀lú àdéhùn tí wọ́n ṣe pẹ̀lú ẹgbẹ́ náà.

‎Nínú àṣẹ tí wọ́n fún àwọn Ìgbákejì Àgbà àwọn yunifásítì ìjọba àpapọ̀, Dókítà Alausa tẹnu mọ́ ìṣiṣẹ́ ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà ìṣẹ́ (CATA).

‎Ó rọ àwọn igbákejì àwọn láti lo àwọn òun èlò tó wà ní ọ̀nà tó tọ́ láti rí i dájú pé wọ́n ṣe àṣeyọrí ìfúnni náà.

Comments are closed.

button