Take a fresh look at your lifestyle.

Nàìjíríà Ṣetán Láti Ṣàgbékalẹ̀ Ohun Alùmọ́nì Agbára Nípasẹ̀ Àjọṣepọ̀ Àwọn Orílẹ̀-èdè Ilẹ̀ Adúláwọ̀

6

 

Ààrẹ Tinubu sọ pé orílẹ-èdè Nàìjíríà ti ṣetan láti darapọ̀ mọ́ àwọn orílẹ-èdè ilẹ̀ Adúláwọ̀ àti alatilẹyin agbaye pẹlu àwọn aladani láti sàgbékalẹ̀ ohùn alumọni agbara to rọrùn láti ní alápapọ̀ to mọ́ toto.

Ààre Nàìjíríà sọ èyí ní ojó isegun ní ilu Abuja ibi to ti sisọ loju eegun ìpàdé agbaye ẹlẹ́kesàn án iru rẹ̀ – 9th Nigeria International Energy Summit, ti àwọn olórí àti ọgá ọgá lẹnu iṣẹ ìjọba peju pese sì lorilede yìí àti kaakiri agbaye.

 

Igbákejì ààrẹ, Kashim Shettima, to soju fún sọ pe, ohun alumọni agbara ni alaafia, ọrọ àti ìdúróṣinṣin agbaye, orílẹ-èdè Naijiria ní afojusun àti lo afẹfẹ gaasi to wọpọ bí ohun eelo epo ayipada sì àwọn ohun eelo alumọni agbara to gbilẹ̀.

 

“Ohun eelo alumọni agbara nilati so agbegbe mọ́ra, ó jẹ kí ọrọ ajé duro daradara àti pé yóò jẹ kí ọjọ ọla dara, yóò fún ilẹ iṣẹ lagbara itaniji, yóò jẹ kí àwọn ilé tàn, yóò jẹ kí igbẹ́kẹ̀lé wà láàárín ìjọba, Oludasẹ́sile àti àwọn ọmọ orílẹ-èdè”.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

 

 

Comments are closed.

button