Àjọ ikọ̀ alalaafia, United Nations peacekeeping mission ní Congo yoo ran ikọ̀ akọkọ rẹ láti mojuto idawọ́ ogun dúró láàrin ìjọba Congo àti ikọ̀ ọlọtẹ
AFC/M23 laipẹ ọjó die to n bọ̀. Minisiri ilé òkèèrè ti Quatar ló sọ èyí ní ọjó Aje lẹyìn iforowero ní Doha.
Igbesẹ̀ etò lati dawo ogún duro
wáyé lẹyìn ija ajaku akata to wáyé ní ìlà oorun.
Ní opin ọsẹ,ohun ija oloro Dírònù ni wọn fi sọ Pápákọ̀ ofurufu ariwa ila oorun ìlú Congo, Kisangani, ìjọba Congo sọ bẹ́ẹ̀.
Ti o bá jẹ ti ikọ̀ AFC/M23, yóò túmọ sì pé ìwọ̀ oòrùn to jina rére ti gbinaya gẹgẹ bí ikọlu sì ijọba Kinshasa.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san