Take a fresh look at your lifestyle.

Abuja Ní Àádọ̀ta Ọdún: Wike Bẹ́rî Fún Àyípadà FCT

14

 

Mínísítà Olu ilu Naijiria, Abuja, FCT, ọgbẹni Nyesom Wike ti gboriyin fún idagbasoke àti ayipada ìlú náà lẹ́yìn àbẹwò rẹ sì àwọn àkànṣe iṣẹ ní ọjó Iṣẹgun ní ọnà láti sami sì ọdún aadọta ìlú Abuja.

Ó sojú abẹ niko pé, ìjọba ààrẹ Tinubu ti mú ki ayípadà to lọ́ọ̀rin to rẹ̀wà débá ìlú náà.

Wike bẹrẹ Irinajo rẹ ni Gishiri, pé yóò di sísí ni ọdún keji sì ìkẹta ìjọba to wà lórí aleefa.

Ó tún lọ si OSEX/Ring Road I area láti sabewo sì Biriji, lẹyìn náà, o lọ si Apo-Wassa sector—
to se pàtàkì fún olùsòwò Ado.

Inu mi dùn fún àwọn nnkan ti mo ń ri yí”- Wike sọ èyí.

… akoko ààrẹ ti yìí ojú ilé FCT padà ṣí rere, o tun sọ èyí.
Gbogbo isẹ yìí lò telé ilana agbekale ìlú Abuja – Abuja Master Plan.”

 

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button