Take a fresh look at your lifestyle.

PDP Gbé Ìgbésẹ̀ Láti Parí Ikùn Sínú Láàrín Àwọn Ọmọ Ẹgbẹ́

80

Ẹgbẹ́ Òṣèlú ‘Peoples Democratic Party PDP’ tí bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ láti yanjú àwọn ikùn sínú láàrin àwọn ọmọ ẹgbẹ́, bí Ìgbìmọ̀ Àwọn Olóòtú (BoT) àti Ìgbìmọ̀ Àwọn Iṣẹ́ tí ẹgbẹ́ náà ṣe ń ṣé ìdánilójú ìṣọ̀kan, láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ìdájọ́ ilé-ẹjọ́ àti láti ìgbaradì fún àpéjọ gbogbogbòò tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́.

‎ Nígbàtí o n sọ̀rọ̀ níbí ìpàdé ọdún karùn-úndínlàádọ́rùn (85th) tí Ìgbimọ Àwọn Olóòtú (BoT) PDP ní Abuja, Alága BoT, Sẹnetọ Mao Ohuabunwa, ṣàpèjúwe ẹgbẹ́ náà gẹgẹ bí ẹyi tó wà ní ipò ẹlẹgẹ, Ó rọ awọn aṣáájú ẹgbẹ́ láti já fún ànfààní ẹgbẹ́ jù ìfẹ ará ẹni lọ.

‎Ohuabunwa sọ pé PDP tí kojú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpèníjà ìpè-ẹjọ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ oṣù láti ọ̀dọ̀ àwọn olórí ẹgbẹ́, ṣùgbọ́n ẹgbẹ́ náà bóri ifẹsẹmulẹ rẹ̀.

‎O wá àwọn ọmọ ẹgbẹ́ láti ṣe ará wọn ní ọkan fún ọjọ́ iwájú ẹgbẹ́ náà.

Comments are closed.

button