Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Aṣojú Ìrètí Tuntun Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Àwọn Olùṣàkóso Ìbílẹ̀ Ní Sokoto

143

Ẹgbẹ́ Àwọn Aṣojú Ìrètí Tuntun ti Ìpínlẹ̀ Sokoto ti ṣe ìfilọ́lẹ̀ àwọn olùṣàkóso ìbílẹ̀ mẹ́tàlélógún láti darí ìgbòkègbodò ètò náà káàkiri ìpínlẹ̀ náà.

‎Ayẹyẹ ìfilọ́lẹ̀ náà, tí a ṣe ní Sokoto, ṣe àmì ìgbésẹ̀ pàtàkì láti fún ìgbìmọ̀ náà lágbára lórí kíkó àwọn ọdọ jọ́ àti lati funni niro nípa àwọn ètò àti àtúnṣe ti Ààrẹ Bola Tinubu, ní gbogbo agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́tàlélógún ní ìpínlẹ̀ náà.

‎Nígbà tí ó ń sọ̀rọ̀ níbí ìfilọ́lẹ̀ náà, olùṣàkóso ìpínlẹ̀ náà, Haruna Sarkin Adiya, ṣàpèjúwe ìgbésẹ náà gẹ́gẹ́ bí àkókò pàtàkì nínú ìrìnàjò àpapọ̀ sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tuntun àti aláásìkí.

Comments are closed.

button