Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom Ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Ọkọ̀ CNG.

75

Gómìnà ìpínlẹ̀ Akwa Ibom Imo Eno ti ṣe Ìfilọ́lẹ̀ Ọkọ̀ irinṣẹ ti o n ló gáàsì CNG ni uyo.

Gómìnà ni èyí wa fún ìdàgbàsókè ìpínlẹ̀ náà láti ri wí pè àwọn ènìyàn wa nínú ìrònú kaakiri ìpínlè náà pàápàá jùlọ ni ètò irinṣẹ́.

Gómìnà Eno so di mímọ̀ wí pè anfààní yìí yóò ṣe ìjoba ìbílẹ̀ okanlelogbon ti o wa ni ìpínlẹ̀ náà.

Ó ni ìjoba ti ṣe ọkọ̀ Àdọ́ọ́ta ti yóò bẹ̀rẹ̀ isẹ́ laipe ti àwọn ènìyàn yóò sí jẹ igbadun re Lai so owó kankan.

Comments are closed.

button