Take a fresh look at your lifestyle.

Albanese Jáwé Olúborí Fún Sáà Kejì Gégébí Alàkóso ‎

9

Anthony Albanese tí jáwé Olúborí láti dárí Orílẹ̀-èdè Australia fún sáà keji gẹ́gêbí Alàkóso Orílẹ̀-èdè náà.

‎ L’àkókò tí kíkà ibo sí ń tẹ̀síwájú fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọjọ́, àwọn àsọtẹlẹ fihàn pé ẹgbẹ́ Labour tí Albanese wà lórí ọnà látí ní ọmọ ẹgbẹ́ tó pọ̀ jùlọ ní ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin, pẹ̀lú bí ẹgbẹ́ àjọṣepọ̀ ‘conservative Liberal-National Coalition’.

Comments are closed.

button