Ààrẹ tẹlẹ rí fún Orílè-èdè Ghana Baba Addo Akufo Addo tí rọ àwọn olóṣèlú Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti darí iwo oòrùn Áfíríkà fún atilẹyin nlá.
Nígbà tí o n sọrọ ni ọjọ̀bọ̀ ni ìlú Abuja níbi ayẹyẹ ìtàn ìgbésí ayé Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹlẹ rí Ibrahim babangida , Akufo Addo tẹnumọ iṣé pàtàkì tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nko ni Ile Áfíríkà.
Akufo Addo ni ohun mọ ohun ti Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà n la koja báyìí sùgbọ́n láì sí iranlọwọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà asán ni Ìdàgbàsókè Ilé Áfíríkà.