Alága elétò Ìdìbò, Independent National Electoral Commission (INEC), Professor Joash Amupitan, ti kópa nibi eto ipade apapọ agbaye ti orílẹ-èdè India to da lórí ijoba àwaarawa àti isakoso idibo – India International Conference on Democracy and Election Management (IICDEM).
Ìpàdé Àgbáyé náà fún Ọ̀jọ̀gbọ́n Amupitan ní ààyè pẹlu àjọ àwọn òṣèlú káàkiri àgbáyé ní ọnà láti mọ ọgbọn atinuda láti ró ọ̀pọ̀ ètò ìdìbò lágbára àti ríró ijọba àwaarawa lágbára.

Ètò sise àgbékalẹ̀, ECINET, ẹ̀rọ àpapọ Kọ̀mpútà to wà lórí ẹrọ alágbèéká àti ìkànnì Wẹ́ẹ̀bù. Àgbékalẹ̀ ètò náà wà fún kíkópa
àwọn ènìyàn nibi ètò ìdìbò ti ìjọba àwaarawa àgbáyé.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san