Ìjoba àpapọ ti gbé òsùbà o Kare fún ayẹyẹ ọdun àṣà ati isẹ wa, ti wọn n pé ni Agungun gẹ́gẹ́ bíi ajọdun to mu ìrépọ̀ ati isokan ba àṣà àti isẹ́ wá ni Orílè-èdè Nàìjíríà àti ni àgbáyé.
Mínísítà fún ọ̀rọ̀ tó nlọ ati ìdanilékọ̀ọ́ Mohammed Idris ló so èyí di mímọ̀ ni àsìkò to n sí ẹ̀tò Ayẹyẹ Ọdun Arungun ti odún yìí ni ìlu Abuja.
Dókítà Suleiman Haruna ni ó sojú mínísítà níbi ayẹyẹ náà ti o sàlàyé wí pè o jẹ ayẹyẹ ti o n ti bẹ̀rẹ̀ láti ọdun 1934 ti o sí n mu ìdàgbàsókè, irẹpọ, àlàáfíà ati iṣọkan ba àwọn ènìyàn lápapò