Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbìmọ̀ Àjọ IMF Parí Àyẹ̀wò Owó Ẹlẹ́kẹ̀rin Orílẹ̀-èdè Ethiopia

88

Ìgbìmò àjọ IMF ti parí àyẹ̀wò ètò owó tó kẹ́yìn fún Orílẹ-èdè Ethiopia.

Ninu akọsilẹ, wọ́n sọ pé ètò náà

yóò fi àye silẹ láti sàn owó tó tó ọ̀kànlélọ́gọ̀ta-lé-nígba Dọ́là fún ìjọba Ethiopia.

Ìjọba ní Addis Ababa ti sọ tẹlẹ pe wọn ti tẹwọ́bọ iwe àdéhùn pẹlu àjọ náà oní Bílíọ̀nù kan Dọ́là agbaye ní ọnà láti ṣe àtúnṣe rẹ lẹyìn ìjíròrò.

Ní ọjọ́ Ọjọ́rú, àjọ IMF sọ pé ètò àdéhùn àkọ́kọ́ sàmìn sì ìgbésẹ̀ tó ṣe pàtàkì ilẹ̀ Ethiopia sí ọ̀nà láti jẹ kí ètò ìyáwó rọrùn kò sì máa lọ bẹ́ẹ̀.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button