Mínísítà fún Ìpínlẹ̀ fún Ise-ọgbin àti Ààbò Oúnjẹ tí Nàìjíríà, Aliyu Sabi Abdullahi, (Baraden Borgu), tí kẹ́dun pẹ̀lú àgbègbè Kasuwan Daji ní Ìjọba ìbílẹ̀ Borgu ní Ìpínlẹ̀ Niger lórí ikọlù tí àwọn oníjàgídíjàgan ṣé si agbègbè náà.
Gẹgẹ bí àwọn ìròyìn ṣe sọ, o jú ènìyàn ogójì àti méjì (42) lọ tí wọn pá nígbà tí àwọn mìíràn f’arapa l’oriṣiriṣi, wọn tún sun ilé àwọn ènìyàn naa àti iye àwọn ènìyàn tí wọ́n jigbe.
Nínú àtẹ̀jáde kán tí Mínísítà náà fọwọ́ si, àwọn ikọlù náà jẹ́ àfihàn ìbàjẹ́ àwọn oníjàgídíjàgan àti àwọn ọlọṣà tó yán láti dá àlàáfíà àti ìgbésí ayé awọn ènìyàn agbègbè náà láàmú ni Borgu ni Ìpínlẹ̀ Niger.