Mínísítà fún ọ̀rọ̀ tó nlọ Alhaji Mohammed Idris so wí pè ẹ̀tọ̀ ìṣúná owó Ọdún 2026 jẹ ohun tí wọ́n fi ọgbọ́n àti làákàyè gbé kalẹ fún àtìlẹ́yìn ijoba Ààrẹ Tinubu.
Nínú ọ̀rọ̀ tó jáde láti ẹnu Mallam Rabiu Ibrahim to jẹ ìgbà Kejì pàtàkì fún ayelujara ni ọjọ́ ìṣẹgun, ṣe àpèjúwe ẹ̀tọ̀ ìṣúná owó náà gẹ́gẹ́ bí àtúnṣe, ilọsiwaju,igbesoke àti àlàáfíà ìjọba Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Idris ni o jẹ anfààní nla fún ijọba àpapọ̀ láti yanjú àwọn ipenija nkán nkán to n kọjú Orílẹ̀-èdè yìí látì igbayi wa
Ó sàlàyé wí pè laipe àwọn ipenija náà yii yóò di ohùn itan.
Ó ní àwon èròngbà nlá ti yóò mú ìdàgbàsókè bá Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nipa ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́, ẹtọ ìṣúná,ilera, ààbò ati bẹbẹ lo ni o wa nínú eto ìṣúná owó náà.
Ó wa rọ àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lati fọwọ́sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú ìjoba kì wọn sì ni sùúrù púpò.